Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 53:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńláòun yóò sì pín ìkógun pẹ̀lú àwọn alágbára,nítorí pé òun jọ̀wọ́ ẹ̀míi rẹ̀ fún ikú,tí a sì kà á mọ́ àwọn alárèékọjáNítorí ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀,ó sì ṣe ìlàjà fún àwọn alárèékọjá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53

Wo Àìsáyà 53:12 ni o tọ