Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 53:11-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Lẹ́yìn ìpọ́njú ẹ̀mí rẹ̀,òun yóò rí ìmọ́lẹ̀, ààyè yóò sì tẹ́ ẹ lọ́rùn;nípa ìmọ rẹ̀ ìránṣẹ́ mi olódodo yóò dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ láre,Òun ni yóò sì ru àìṣedédé wọn

12. Nítorí náà èmi yóò fún un ní ìpín pẹ̀lú àwọn ẹni ńláòun yóò sì pín ìkógun pẹ̀lú àwọn alágbára,nítorí pé òun jọ̀wọ́ ẹ̀míi rẹ̀ fún ikú,tí a sì kà á mọ́ àwọn alárèékọjáNítorí ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀,ó sì ṣe ìlàjà fún àwọn alárèékọjá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53