Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 52:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni ó ṣe dára tó lórí òkèẹṣẹ̀ àwọn tí ó mú ìyìn rere ayọ̀ wá,tí wọ́n kéde àlàáfíà,tí ó mú ìyìn rere wá,tí ó kéde ìgbàlà,tí ó sọ fún Ṣíhónì pé,“Ọlọ́run rẹ ń jọba!”

Ka pipe ipin Àìsáyà 52

Wo Àìsáyà 52:7 ni o tọ