Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 52:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti ní àkókò yìí, kí ni mo ní níbí?” ni Olúwa wí.“Nítorí a ti kó àwọn ènìyàn mi lọ lọ́fẹ̀ẹ́,àwọn tí ó sì ń jọba lé wọn fi wọ́n ṣẹlẹ́yà,”ni Olúwa wí.“Àti ní ọjọọjọ́orúkọ mi ni a ṣọ̀rọ̀ òdì sí nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Àìsáyà 52

Wo Àìsáyà 52:5 ni o tọ