Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 52:13-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Kíyèsí i, ìránṣẹ́ mi yóò hùwà ọlọgbọ́n;òun ni a ó gbé ṣókè tí a ó sì gbégaa ó sì gbé e lékè gidigidi.

14. Gẹ́gẹ́ bí a ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wọ́n ń bọlá fún un—ìwò ojú rẹ ni a ti bà jẹ́ kọjá ti ẹnìkẹ́ni àti ìrísí rẹ̀ ní a ti bàjẹ́ kọjá ohun tí ènìyàn ń fẹ́

15. bẹ́ẹ̀ ni yóò ṣe bomirin àwọn orílẹ̀ èdè ká,àwọn ọba yóò sì pa ẹnu wọn mọ́ nítoríi rẹ̀.Nítorí ohun tí a kò sọ fún wọn, wọn yóò rí i,àti ohun tí wọn kò tí ì gbọ́, ni yóò sì yé wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 52