Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 52:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kì yóò yára kúròtàbí kí ẹ ṣáré lọ;nítorí Olúwa ni yóò ṣíwájúu yín lọ,Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni yóò sì ṣe ààbò lẹ́yìn ín yín.

Ka pipe ipin Àìsáyà 52

Wo Àìsáyà 52:12 ni o tọ