Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 52:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ túká, ẹ túká, ẹ jáde kúrò níhìnínyìí!Ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́ kan!Ẹ jáde kúrò nínú rẹ̀ kí ẹ sì di mímọ́,ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé ohun èlò Olúwa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 52

Wo Àìsáyà 52:11 ni o tọ