Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 51:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí ìwọ sì gbàgbé Olúwa ẹlẹ́dàá rẹ,ẹni tí ó ta àwọn ọ̀runtí ó sì fi ìpìlẹ̀ ayé ṣọlẹ̀,tí ẹ sì ń gbé nínú ìpayà lójoojúmọ́nítorí ìbínú àwọn aninilára,tí wọ́n sì gbọ́kàn lé ipanirun?Nítorí ibo ni ìbínú àwọn aninilára gbé wà?

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:13 ni o tọ