Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 51:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi, àní Èmi, èmi ni ẹni tí ó tù ọ́ nínú.Ta ni ọ́ tí o fi ń bẹ̀rù ènìyàn ẹlẹ́ran-ara,àti ọmọ ènìyàn, tí ó jẹ́ koríko lásán,

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:12 ni o tọ