Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 51:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin tí ó ń lépa òdodoàti ẹ̀yin tí ń wá Olúwa:Wo àpáta, nínú èyí tí a ti gé yín jádeàti ihò òkúta níbi tí a ti gbẹ́ yín jáde;

2. ẹ wo Ábúráhámù baba yín,àti Ṣérà, ẹni tó bí i yín.Nígbà tí mo pè é, òun nìkan ni,Èmi sì bùkún un, mo sì sọ́ọ́ di ọ̀pọ̀lọpọ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 51