Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 51:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dájúdájú, Olúwa yóò tu Ṣíhónì nínúyóò sì bojú àánú wo gbogbo ahoro rẹ̀;Òun yóò sọ gbogbo aṣálẹ̀ rẹ̀ di Ídẹ́nì,gbogbo ìgbòrò rẹ̀ yóò rí bí ọgbà Olúwa.Ayọ̀ àti inúdídùn ni a ó rí nínú rẹ̀,ọpẹ́ àti ariwo orín kíkọ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:3 ni o tọ