Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ní hápù àti láà níbi àṣè wọn,tamborínìn òun fèrè àti wáìnì,ṣùgbọ́n wọn kò ka iṣẹ́ Olúwa sí,kò sí ìbọ̀wọ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:12 ni o tọ