Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọba ni yóò jẹ́ alágbàtọ́-baba fún ọ,àwọn ayaba wọn ni yóò sì jẹ́ ìyá-alágbàtọ́.Wọn yóò foríbalẹ̀ ní iwájú rẹ̀ pẹ̀lú ojú wọn dídàbolẹ̀;wọn yóò máa lá èrùpẹ̀ lẹ́bàá ẹṣẹ̀ rẹ.Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé Èmi ni Olúwa;gbogbo àwọn tí wọ́n ní ìrètí nínú mini a kì yóò jákulẹ̀.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:23 ni o tọ