Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí níyìí:“Kíyèsí i, Èmi yóò késí àwọn aláìkọlàÈmi yóò gbé àṣíá mi ṣókè sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn;Wọn yóò kó àwọn ọmọkùnrin yín wá ní apá wọnwọn yóò sì gbé àwọn ọ̀dọ́mọbìnrinní èjìká wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:22 ni o tọ