Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 48:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A dá wọn ní àkókò yìí kì í ṣe láti ìgbà pípẹ́ìwọ kò tí ì gbọ́ nípa wọn títí di òní.Nítorí náà, ìwọ kò lè sọ pé,‘Bẹ́ẹ̀ ni, mo mọ̀ nípa wọn.’

Ka pipe ipin Àìsáyà 48

Wo Àìsáyà 48:7 ni o tọ