Òrùngbẹ kò gbẹ wọ́n nígbà tí ó kó wọnkọjá nínú ihà;ó jẹ́ kí omi ó sàn fún wọn láti inú àpáta;ó fọ́ àpátaomi sì tú jáde.