Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 48:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi Bábílónì sílẹ̀,sá fún àwọn ará Bábílónì,ṣe ìfilọ̀ èyí pẹ̀lú ariwo ayọ̀kí o sì kéde rẹ̀.Rán an jáde lọ sí òpin ilẹ̀ ayé;wí pé, “Olúwa ti dá ìránṣẹ́ rẹ̀ Jákọ́bù nídè.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 48

Wo Àìsáyà 48:20 ni o tọ