Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 48:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Tẹ́tí sí èyí, Ìwọ ilée Jákọ́bù,ìwọ tí a ń pè pẹ̀lú orúkọ Ísírẹ́lìtí o sì wá láti ẹ̀ka Júdà,ìwọ tí ò ń búra ní orúkọ Olúwatí o sì ń pe Ọlọ́run Ísírẹ́lìṣùgbọ́n kì í ṣe ní òtítọ́ àti òdodo

2. Ìwọ tí ò ń pe ara rẹ ní ọmọ ìlú mímọ́ n nìtí o sì gbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run Ísírẹ́lì— Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ̀:

Ka pipe ipin Àìsáyà 48