Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 48:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tẹ́tí sí èyí, Ìwọ ilée Jákọ́bù,ìwọ tí a ń pè pẹ̀lú orúkọ Ísírẹ́lìtí o sì wá láti ẹ̀ka Júdà,ìwọ tí ò ń búra ní orúkọ Olúwatí o sì ń pe Ọlọ́run Ísírẹ́lìṣùgbọ́n kì í ṣe ní òtítọ́ àti òdodo

Ka pipe ipin Àìsáyà 48

Wo Àìsáyà 48:1 ni o tọ