Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 47:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìparun yóò dé bá ọbẹ́ẹ̀ ni ìwọ kì yóò mọ ọ̀nà láti ré e kúrò.Àjálù kan yóò ṣubú lù ọ́tí o kì yóò le è fi ètùtù ré kúrò;òfò kan tí o kò le ròtì niyóò wá lójijì sí oríì rẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 47

Wo Àìsáyà 47:11 ni o tọ