Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 46:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́lì tẹríi rẹ̀ ba, Nébò bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀;àwọn ère wọn ni àwọn ẹranko rù.Àwọn ère tí wọ́n ń rù káàkiri ti diàjàgà sí wọn lọ́rùn,ẹrù fún àwọn tí àárẹ̀ mú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 46

Wo Àìsáyà 46:1 ni o tọ