Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 43:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ní ìsinsìn yìí, ohun tí Olúwa wí nìyìíẹni tí ó dá ọ, Ìwọ Jákọ́bùẹni tí ó mọ ọ́, Ìwọ Ísírẹ́lì:“Má bẹ̀rù, nítorí Èmi ti dá ọ nídè;Èmi ti pè ọ́ ní orúkọtèmi ni ìwọ ṣe.

Ka pipe ipin Àìsáyà 43

Wo Àìsáyà 43:1 ni o tọ