Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 41:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ta ni ó ti ru ẹnìkan ṣókè láti ìlà-oòrùn wá,tí ó pè é ní òdodo sí iṣẹ́ tirẹ̀?Ó gbé àwọn orílẹ̀ èdè lé e lọ́wọ́ó sì ṣẹ́gun àwọn ọba níwájúu rẹ̀.Ó sọ wọ́n di erùpẹ̀ pẹ̀lú idà rẹ̀,láti kù ú níyàngbò pẹ̀lú ọrun rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:2 ni o tọ