Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 41:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ẹ dákẹ́ jẹ́ ẹ́ níwájúù mi ẹ̀yin erékùṣù!Jẹ́ kí àwọn orílẹ̀ èdè tún agbára wọn ṣe!Jẹ́ kí wọn wá ṣíwájú kí wọn sọ̀rọ̀:Jẹ́ kí a pàdé pọ̀ ní ibi ìdájọ́.

2. “Ta ni ó ti ru ẹnìkan ṣókè láti ìlà-oòrùn wá,tí ó pè é ní òdodo sí iṣẹ́ tirẹ̀?Ó gbé àwọn orílẹ̀ èdè lé e lọ́wọ́ó sì ṣẹ́gun àwọn ọba níwájúu rẹ̀.Ó sọ wọ́n di erùpẹ̀ pẹ̀lú idà rẹ̀,láti kù ú níyàngbò pẹ̀lú ọrun rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41