Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni yóò jẹ́ ààbò àti òjìji kúrò lọ́wọ́ ooru ọ̀sán, àti ààbò òun ibi ìsádi kúrò lọ́wọ́ ìjì àti òjò.

Ka pipe ipin Àìsáyà 4

Wo Àìsáyà 4:6 ni o tọ