Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 39:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì náà sì béèrè pé, “Kí ni wọ́n rí nínú ààfin rẹ?”“Wọ́n rí gbogbo ohun tí ó wà nínú ààfin mi” ni ìdáhùn Heṣekáyà. “Kò sí ohun kankan nínú ìṣúra mi tí èmi kò fi hàn wọ́n.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 39

Wo Àìsáyà 39:4 ni o tọ