Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 39:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Heṣekáyà gba àwọn ikọ̀ yìí tayọ̀ tayọ̀, ó sì fi àwọn nǹkan tí ó wà nínú yàrá ìpanǹkan mọ́ hàn wọn—sílífà, wúrà, ohun olóòórùn dídùn, òróró dídára, gbogbo nǹkan ogun rẹ̀ àti ohun gbogbo tí ó wà nínú ìṣúra rẹ̀ kò sí ohunkóhun tí ó wà nínú ààfin rẹ̀ tàbí ní ìjọba rẹ̀ tí Heṣekáyà kò fi hàn wọ́n.

Ka pipe ipin Àìsáyà 39

Wo Àìsáyà 39:2 ni o tọ