Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 38:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Rántí, Ìwọ Olúwa, bí mo ti rìn pẹ̀lú òtítọ́ níwájúù rẹ, àti bí mo ti fi ọkàn dídúró ṣinṣin ṣe ohun tí ó dára ní ojúù rẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni Heṣekáyà sì ṣunkún kíkorò.

Ka pipe ipin Àìsáyà 38

Wo Àìsáyà 38:3 ni o tọ