Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 38:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi fi ṣùúrù dúró títí di àfẹ̀mọ́jú,ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí kìnnìún ó ti fọ́ gbogbo egungun mi;ọ̀ṣán àti òru ni ìwọ fi ṣe òpin mi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 38

Wo Àìsáyà 38:13 ni o tọ