Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣé o kò tí ì gbọ́?Tipẹ́ tipẹ́ ni mo ti fìdíi rẹ̀ mulẹ̀.Láti ìgbà pípẹ́ ni mo ti ṣètò rẹ̀;ní àkókò yìí ni mo mú wá sí ìmúṣẹ,pé o ti sọ àwọn ìlú olódi diàkójọpọ̀ àwọn òkúta

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:26 ni o tọ