Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 35:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

òun yóò bẹ́ná jáde;yóò yọ ayọ̀ ńlá ńlá yóò sì kígbe fún ayọ̀.Ògo Lẹ́bánónì ni a ó fi fún un,ọlá ńlá Kámẹ́lì àti Ṣárónì;wọn yóò rí ògo Olúwa,àti ọlá ńlá Ọlọ́run wa.

Ka pipe ipin Àìsáyà 35

Wo Àìsáyà 35:2 ni o tọ