Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:22-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Nítorí Olúwa ni onídàájọ́ wa, Olúwa ni olófin wa, Olúwa òun ni ọba wa;òun ni ẹni tí yóò gbà wá là.

23. Gbogbo okùn rẹ ni ó ti dẹ̀Ìgbókùnró kò fìdímúlẹ̀,wọn kò taṣọ agbọ́kọ̀rìn,lẹ́yìn náà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìkógun ni a ó pínàní arọ pẹ̀lú yóò ru ìkógun lọ.

24. Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó ń gbé Ṣíhónì tí yóòwí pé, “èmi ń sàìsàn,”àti gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ àwọn tí ń gbé ibẹ̀ni a ó fojúfòdá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33