Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 33:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ọkùnrin náà nìyìí tí yóò gbé ní ibi gíga,ẹni tí ààbò rẹ̀ yóò jẹ́ òkè ńlá olódi.A ó máa mú àkàrà rẹ̀ wábẹ́ẹ̀ ni omi kì yóò wọ́n ọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 33

Wo Àìsáyà 33:16 ni o tọ