Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 32:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnì kọ̀ọ̀kan yóò dàbí ìdáàbòbò lọ́wọ́ afẹ́fẹ́àti ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì,gẹ́gẹ́ bí odò omi nínú aṣálẹ̀àti òjìji àpáta ńlá ní ilẹ̀ òrùngbẹ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32

Wo Àìsáyà 32:2 ni o tọ