Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 32:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Wòó, ọba kan yóò jẹ nínú òdodoàwọn olórí yóò máa ṣàkóso ní ìdájọ́.

2. Ẹnì kọ̀ọ̀kan yóò dàbí ìdáàbòbò lọ́wọ́ afẹ́fẹ́àti ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì,gẹ́gẹ́ bí odò omi nínú aṣálẹ̀àti òjìji àpáta ńlá ní ilẹ̀ òrùngbẹ.

3. Nígbà náà ni ojú àwọn tí ó rí kò ní pàdé mọ́,àti etí àwọn tí ó gbọ́ yóò tẹ́tí sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 32