Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 30:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ti tọ́jú Tófẹ́tì sílẹ̀ tipẹ́tipẹ́,a ti tọ́jú rẹ̀ sílẹ̀ fún ọba.Ojú ààrò rẹ̀ ni a ti gbẹ́ jìn tí ó sì fẹ̀,pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ iná àti igi ìdáná;èémí Olúwa,gẹ́gẹ́ bí ìsàn ṣúfúrù tí ń jó ṣe mú un gbiná.

Ka pipe ipin Àìsáyà 30

Wo Àìsáyà 30:33 ni o tọ