Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 29:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun yóò wápẹ̀lú àrá, ilẹ̀ ríri àti ariwo ńláàti ẹ̀fúúfù líle àti iná ajónirunorílẹ̀ èdè tí ó bá Áríẹ́lì jà,tí ó dojú ìjà kọ òun àti ilé olódì rẹ̀tí ó sì dó tì í,yóò dàbí ẹni pé nínú àlá,bí ìran ní òru

Ka pipe ipin Àìsáyà 29

Wo Àìsáyà 29:6 ni o tọ