Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 29:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún àwọn tí ó lọ sí ọ̀gbunláti fi ètò wọn pamọ́ kúrò lójú Olúwa,tí wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ẹ wọn nínú òkùnkùntí wọ́n sì rò pé,“Ta ló rí wa? Ta ni yóò mọ̀?”

Ka pipe ipin Àìsáyà 29

Wo Àìsáyà 29:15 ni o tọ