Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 27:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò fi idà rẹ̀ jẹni níyàidà rẹ̀ amúbí-iná tí ó tóbi tí ó sì lágbáraLẹ́fíátanì ejò tí ń yọ̀ tẹ̀ẹ̀rẹ̀ n nì,Lẹ́fíátanì ejò tí ń lọ́ bìrìkìtì;Òun yóò sì pa ewèlè inú òkun náà.

2. Ní ọjọ́ náà“Kọrin nípa ọgbà-àjàrà eléso kan.

3. ÈMI Olúwa ń bojú tó o,Mo ń bomirin ín láti ìgbàdégbà.Mò ń sọ́ ọ tọ̀sán tòrukí ẹnikẹ́ni má ba à pa á lára.

Ka pipe ipin Àìsáyà 27