Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò fi idà rẹ̀ jẹni níyàidà rẹ̀ amúbí-iná tí ó tóbi tí ó sì lágbáraLẹ́fíátanì ejò tí ń yọ̀ tẹ̀ẹ̀rẹ̀ n nì,Lẹ́fíátanì ejò tí ń lọ́ bìrìkìtì;Òun yóò sì pa ewèlè inú òkun náà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 27

Wo Àìsáyà 27:1 ni o tọ