Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 25:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Ọwọ́ Olúwa yóò sinmi lé orí òkè yìíṣùgbọ́n a ó tẹ Móábù mọ́lẹ̀ lábẹ́ ẹṣẹ̀ rẹ̀;gẹ́gẹ́ bí a ti gún koríko mọ́lẹ̀ di ajílẹ̀.

11. Wọn yóò na ọwọ́ọ wọn jáde nínú un rẹ̀,gẹ́gẹ́ bí òmùwẹ̀ tí ń na ọwọ́ọ rẹ̀jáde láti lúwẹ̀ẹ́.Ọlọ́run yóò mú ìgbéraga wọn wálẹ̀bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìṣeféfé wà ọwọ́ ọ wọn.

12. Òun yóò sì bi gbogbo ògiri gíga alágbára yín lulẹ̀wọn yóò sì wà nílẹ̀Òun yóò sì mú wọn wá si ilẹ̀,àní sí erùpẹ̀ lásán.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25