Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 25:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ Olúwa yóò sinmi lé orí òkè yìíṣùgbọ́n a ó tẹ Móábù mọ́lẹ̀ lábẹ́ ẹṣẹ̀ rẹ̀;gẹ́gẹ́ bí a ti gún koríko mọ́lẹ̀ di ajílẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 25

Wo Àìsáyà 25:10 ni o tọ