Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ní ọjọ́ kantí rúkèrúdò, rògbòdìyàn àti ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ní àfonífojì ìmọ̀,ọjọ́ tí a ń wó ògiri lulẹ̀àti síṣun ẹkún lọ sí àwọn orí òkè.

Ka pipe ipin Àìsáyà 22

Wo Àìsáyà 22:5 ni o tọ