Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 22:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ ìmọ̀ tí ó jẹ mọ́ àfonífojì ti ìran:Kí ni ó ń dààmú un yín báyìí,tí gbogbo yín fi gun orí òrùlé lọ,

2. Ìwọ ìlú tí ó kún fún dàrúdàpọ̀,Ìwọ ìlú rúkèrúdò òun rògbòdìyànÀwọn tó ṣubú nínú un yín ni a kò fi idà pa,tàbí ojú ogun ni wọ́n kú sí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 22