Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 20:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ní etí òkun yóò wí pé, ‘Wo ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ sí àwọn tí a ti gbọ́kànlé, àwọn tí a sá tọ̀ lọ fún ìrànlọ́wọ́ àti ìtúsílẹ̀ láti ọwọ́ ọba Ásíríà! Báwo ni a ó ṣe sálà?’ ”

Ka pipe ipin Àìsáyà 20

Wo Àìsáyà 20:6 ni o tọ