Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ní àkókò náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa ti ẹnu Àìṣáyà ọmọ Ámósì jáde. Ó sọ fún un pé, “Mú aṣọ ọ̀fọ̀ kúrò ní araà rẹ kí o sì bọ́ ṣálúbàtà kúrò ní ẹṣẹ̀ rẹ.” Ó sì ṣe bẹ́ẹ̀, ó ń lọ káàkiri ní ìhòòhò àti láì wọ bàtà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 20

Wo Àìsáyà 20:2 ni o tọ