Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 20:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọdún tí ọ̀gágun, tí Ṣágónì ọba Ásíríà rán an, wá sí Ásídódù, ó kọ lùú ó sì kó o—

2. ní àkókò náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa ti ẹnu Àìṣáyà ọmọ Ámósì jáde. Ó sọ fún un pé, “Mú aṣọ ọ̀fọ̀ kúrò ní araà rẹ kí o sì bọ́ ṣálúbàtà kúrò ní ẹṣẹ̀ rẹ.” Ó sì ṣe bẹ́ẹ̀, ó ń lọ káàkiri ní ìhòòhò àti láì wọ bàtà.

3. Lẹ́yìn náà ni Olúwa wí pé, “Gẹ́gẹ́ bí Ìránṣẹ́ mi Àìsáyà ti lọ káàkiri ní ìhòòhò àti láì wọ bàtà fún ọdún mẹ́ta, gẹ́gẹ́ bí àmì àti àpẹẹrẹ sí Éjíbítì àti Kúṣì,

Ka pipe ipin Àìsáyà 20