Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ wọ́n kún fún fàdákà àti wúràìṣúra wọn kò sì ní òpin.Ilẹ̀ ẹ wọn kún fún ẹṣin,kẹ̀kẹ́ ogun wọn kò sì lópin.

Ka pipe ipin Àìsáyà 2

Wo Àìsáyà 2:7 ni o tọ