Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ Júdà yóò da wárìwàrì jó àwọn ará Éjíbítì; gbogbo àwọn tí a bá ti dárúkọ Júdà létíi wọn ni yóò wárìrì, nítorí ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun gbérò láti ṣe sí wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:17 ni o tọ