Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 19:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ náà ni àwọn ará Éjíbítì yóò dàbí obìnrin. Wọn yóò gbọ̀n jìnnìjìnnì pẹ̀lú ẹ̀rù nítorí ọwọ́ Olúwa àwọn ọmọ-ogun tí a gbé sókè sí wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 19

Wo Àìsáyà 19:16 ni o tọ